
ikoko akufo - beautiful nubia lyrics
ikoko akufo, o d’ero akitan o
ikoko to fo o, o ti dero akitan o
monomono ya lu’gi, oro wo ‘nu ilu o
itiju bi aso akisa lo ma ri o
o d’oro agbagba o, o d’eru f’ologbon
o d’owo awon agba o, o d’eru f’ologbon
ilu orita o
ilu alaafia
mo ni t’e ba de’be
e ba mi ki won o
gbogbo wa la o f’ayo de ‘le
gbogbo wa la o f’ayo de ‘le wa
mo ni t’e ba ri o
e ba nki awero yen o
omoge awelewa to nda ni l’orun o
ile owo ni o wo s’aya
ile ola ni o wo s’aya o
seb’ade ori oko ni won
obinrin to n’iwa t’o l’ewa
iwuri obi ni won o ma je
mobinrin to gb’eko to mu lo
ori re dara, ori re sunwon, o d’adufe olori oko
ori re dara, ori re sunwon, o d’abefe o
ikoko to fo i s’oun a mu se’be
ikoko to fo i s’oun a mu to’le
ikoko to fo i s’oun a mu r’odo
ikoko to fo i s’oun a mu yan’gan
ibadi aran d’eni a mu se yeye o
bi eye ti o l’apa
ibadi aran d’eni a mu se yeye o
o ba ma i lo o
o ba ma i lo o
duro se’un obinrin nse
o ba ma i lo o
awero o ba ma i lo o
gb’aye se’un obinrin nse
o ba duro f’inu sh’oyun
duro se’un obinrin nse
o ba gb’aye feyin gbomopon
gb’aye se’un obinrin nse
o ba ma i lo o
o ba ma i lo o
duro se’un obinrin nse
ilu orita o
ilu alaafia
mo ni t’e ba de’be
e ba mi ki won o
gbogbo wa la o f’ayo de ‘le
gbogbo wa la o f’ayo de ‘le wa
mo ni t’e ba ri o
e ba nki awero yen o
omoge awelewa to nda ni l’orun o
ile owo ni o wo s’aya
ile ola ni o wo s’aya o
Random Song Lyrics :
- la nave del olvido - vikki carr lyrics
- path - dungaree lyrics
- poď so mnou - imt smile lyrics
- jælvig lænt 2019 - juur lyrics
- kno dat - killah threat lyrics
- holy roller - the blank tapes lyrics
- в порядке - file x bruh lyrics
- break through this wall - all good things lyrics
- danke - eno lyrics
- non si accorgerà - stadio lyrics