
ba nu so - brymo lyrics
Loading...
[verse 1]
abéré á lo
abéré á lo
k’ó nà okùn ó tó dí ò
a ò ní dé bá won
a ò ní dé bá won
ení bá ní a máà de ò
[hook/chorus]
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
[verse 2]
omijé á gbe
omijé á gbe
ìbànújé á dèrin ò
eniafé
eniafé lamò o
a ò mo’ni tó fé ni ò
[hook/chorus]
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
[verse 3]
ení bá ma b’ésù jeun
síbíi rè á gùn gan
eni ò mò wáwù
óma tee
òsèlú mà ló layé ò
[hook/chorus]
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
[verse 4]
èyin ará
ewá gbó òò
òrò kan se ùrùn ùrùn nínú iii
sé kín só
kín só
ká bá’núso
[hook/chorus/outro]
bá’núso
n’òní b’enìyan só
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
Random Song Lyrics :
- cut you out - reddy redd lyrics
- if she tale zelle? - mt ty & nate frxsca lyrics
- caroling - fitz and the tantrums lyrics
- 冬の桜 (winter cherry blossoms) - apoki lyrics
- santa played the autoharp - the stonemans lyrics
- hold u - big u on the beat lyrics
- el capitan, act iii: "come, isabel" - steven byess & ohio light opera lyrics
- wait for me - original cast of the time traveller's wife: the musical lyrics
- woah - ceasefire (ita) lyrics
- save me - david end lyrics