
ọkùnrin mẹ́ta (ẹ̀dùn ọkàn) - brymo lyrics
Loading...
gbemi san le
ko mi sita
fami lewu ya
temi lorun pa
eniyan lasan ni mo je
mo fuye bi paper
iji ja lodo
o gbemi lo soko
edun okan
ohun lokan
gbemi lo sibi tokan
oga ta oga o ta
olopa gba riba kasa
edun okan
ohun lokan
gbemi lo ibi mohun lo
edun okan
fun mi lokan
okunrin meta debi ti mo n lo
emi ni imole
olukunkun wo gbo lo
mo fa lewuya
mo te lorun pa
eniyan lasan mi o je
mo wiwo bi ésan
emi ni iji to ja lodo
to gboba won lo soko
edun okan
ohun lokan
gbemi lo sibi tokan
oga ta oga o ta
olopa gba riba kasa
edun okan
ohun lokan
gbemi lo ibi mohun lo
edun okan
fun mi lokan
okunrin meta debi ti mo n lo
edun okan
ohun lokan
gbemi lo sibi tokan
oga ta oga o ta
okunrin meta debi ti mo n lo
Random Song Lyrics :
- el andariego - cornelio reyna lyrics
- it's all about you - dodie lyrics
- frontin' - live at the bbc / 2004 - jamie cullum lyrics
- so - ny - fab louso lyrics
- string around my finger - the well pennies lyrics
- the boss - slim thug lyrics
- quisiera decirte - daniel santacruz lyrics
- ole, dole, doff - antonio d lyrics
- vì ai - wendy thảo lyrics
- type of shit i be on - jae millz lyrics