
ọlanrewaju - brymo lyrics
verse 1
igba o lọ bi orere
bo ba koro oṣi maa dun ah
eni to ni suuru kii ṣeyan kekere
bo ba kan lẹ, oṣi maa goke ah
boo ba ṣe un tọ fe, won maa kẹyin si e (ẹh a ẹh)
bo ba ṣe tirẹ o, o ma jẹ ire fun ẹ
chorus
ọlanrewaju ọmọ ọba
e ma suure da gba won ni ko o ṣe were, roora ṣe
bo ba koro oṣi maa dun ah
e ma suure da gba oo
olooto ko ni ku si bi ọtẹ ooo
olanrewaju ọmọ mi, e ma suure da gba oo
igba o lọ bi orere
bọmọde oku oo, oṣi maa da gba
ṣọra funja, ṣọ ra fẹgbẹkẹgbẹ
oun tio to o, oṣi maa pọ da nu
gbogbo eni abi lo ma ku
iwa ta a wu lo ma ku
ọlanrewaju ọmọ oba, e ma suure da gba o
won ni ko ṣe were, roora ṣe
e ma suure da gba oo
olooto ko ni ku sibi ọtẹ oo
ọlanrewaju ọmọ mi, e ma suure da gba o
olooto ko ni ku sipo ika oo
olooto ko ni ku sibi ote oo
ọlanrewaju ọmọ ọba, ee ma suure dagba oo
ọlanrewaju ọmọ mi, ee ma suure da gba oo
Random Song Lyrics :
- sad song - nicole rayy lyrics
- names - mackenzie shivers lyrics
- throw it back (abow) - tariop lyrics
- final duet (fan lyrics) - or3o lyrics
- sharks - sam kays lyrics
- it never stop - saint punk lyrics
- язык - интернал (internal) lyrics
- pretesto - bautista lyrics
- make me something i'm not - the flattened soles lyrics
- ainda nos temos - syro (prt) lyrics