
oluranlowo - by singers lyrics
Loading...
[verse 1]
angeli bi eniyan
eniyan bi angeli o
oluranlowo kan
t’o nu omije mi nu
t’o gba’so iya lara mi
baba…
ran won simi o
ran won simi o
[verse 2]
awa nwo oju re fun iranlowo
mase je k’awa lo lofo…
kosi eni wa o wa
to lo lowo ofo
mase je kawa lo lofo
[chorus]
eniyan tio waye ti kori iranlowo
owa ye asan ni o…
ran won simi o ran won simi o
alejo oloore tio ran mi lowo
ran won simi o ran won simi o
alejo alaanu tio gbemi dide
Random Song Lyrics :
- waiting room - logan matthew barnes lyrics
- i see it all (remix) - taniathetwin ×fedarro lyrics
- benedetto l'inferno - michele canova lyrics
- rock house - conway twitty lyrics
- matter anymore - t4ncredi lyrics
- bir ihtimal daha var - resul dindar lyrics
- asian money - eltuum lyrics
- мазохист (masochist) - fkurse lyrics
- la candela viva - hugel, jude & frank & twolate lyrics
- you wear it well - ali campbell lyrics