
agbalagbi - oluwamillar lyrics
…
ẹ ti gbọ́ nípa àgbàlágbì
àgbàlágbì tó ju àgbàlágbà lọ
èmi nìí
jàkùmọ̀ wọ̀lú wọ́n paramọ́
àwọn wádà? wọ́n ti sápamó̩ (wọ́n ti lo̩)
málo̩ máa fà, wábi ságbà lọ (ehn)
àgbàlágbì ju àgbàlágbà lọ
jàkùmọ̀ wọ̀lú wọ́n paramọ́
àwọn wádà? wọ́n ti sápamó̩ (wọ́n ti lo̩)
málo̩ máa fà, wábi ságbà lọ (ehn)
àgbàlágbì ju àgbàlágbà lọ
àgbàlágbì j’àgbàlá … (yeah)
àgbàlágbì j’àgbàlá … (yeah)
àgbàlágbì ju àgbàlágbà lọ
ẹ ti mọ̀ p’émi ni father wọn
àgbàlágbì j’àgbàlá … (yeah)
àgbàlágbì ju àgbàlágbà lọ
àgbàlágbì j’àgbàlá … (yeah)
ẹ ti mọ̀ p’émi ni father wọn
bóju yín fọ́, ṣétí ẹ̀yin wèrè wọ̀nyìí tún di ni?
your papa báwajà? ọ̀pàpàparadà
wòó, ó ti lọ bíi houdini
àwọn tèmi ń para lójú méjèèjì
ṣe wèrè kóo r’ọ̀run arákeji
ẹ̀mí yín á gbọ̀n, ẹ̀ẹ́ súré lénìí
guardiola ni, wọn màá ń jáde si
dawgs might chat
say they thugs, my bad
wọ́n láwọn wèrè ní guns, like what?
rap mi n shank mi, man mi
i dey keep am on, like 5 wey snooze offside trap
no go cross my path
alayé, i dey on my guard
and no bros, we ain’t on like that
t’ọ́n bá tọ́jà wa, i go on vini mode, i dey murk right back
ọmọlọ́mọ
as me enter the place i carry like 38 kele
wọ́n ké gb’ọ́mọ gb’ọ́mọ
ìgara mi wọ sánmọ sánmọ
kò mà common, common
n*gga c’mon c’mon
síbẹ̀ síbẹ̀ na warm up, warm up
see them come up, come up
tàwọn tán form naamo
tàwọn tán gbọ́, tán mọ̀
t’àrọ́mọ d’ọ́mọ wọn, ò tó sum up, sum up
miì kú rán wọn, rán wọn
f’ibi rán wọn, rán wọn
l’árèmabọ̀, ma bọ̀
wọ́n máa sán lọ, sán lọ
èmi náà kọ́, náà kọ́
ọmọ tán ń sọ, tán ń sọ
ọmọ́ j’ọmọ s’ọ́mọ, kán má f’ọmọ w’ọ́mọ
kán máa kọ́ lọ, kọ́ lọ
kán máa fọ́ lọ, fọ́ lọ
kí sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ máa sọ́ lọ, sọ́ lọ
on my grind, moti b’ọ́ṣọ s’ọ́lo
bout the pounds k’ápò jọ̀lọ̀ jọ̀lọ̀
never bọ̀lọ̀ bọ̀lọ̀
wọn lè ever dàbí
bí n ṣe ń bọ̀, wọn lè ever sabi
sutanna, àt’àbẹ́là, quwwah wà my brеdda
mo dẹ̀ ti f’iná ṣá tùràrí
lókè lókè l’ọ́lá alúwàràbí
ká gb’ọpẹ́ ni, ká ka surah si
kátún ṣ’àmín, ta bá ṣ’àdúrà si
ọmọ ọpẹ́ ò ní wá moolah tì
jàkùmọ̀ wọ̀lú wọ́n paramọ́
àwọn wádà? wọ́n ti sápamó̩ (wọ́n ti lo̩)
málo̩ máa fà, wábi ságbà lọ (ehn)
àgbàlágbì ju àgbàlágbà lọ
jàkùmọ̀ wọ̀lú wọ́n paramọ́
àwọn wádà? wọ́n ti sápamó̩ (wọ́n ti lo̩)
málo̩ máa fà, wábi ságbà lọ (ehn)
àgbàlágbì ju àgbàlágbà lọ
àgbàlágbì j’àgbàlá … (yeah)
àgbàlágbì j’àgbàlá … (yеah)
àgbàlágbì ju àgbàlágbà lọ
ẹ ti mọ̀ p’émi ni father wọn
àgbàlágbì j’àgbàlá … (yeah)
àgbàlágbì ju àgbàlágbà lọ
àgbàlágbì j’àgbàlá … (yeah)
ẹ ti mọ̀ p’émi ni father wọn
[crowd joins]
…
Random Song Lyrics :
- 這次沒有標題 (this time no title) - 李杰明 w.m.l lyrics
- why? - asia graves lyrics
- old graves (feat. patrick schneeweis & sole) - ceschi lyrics
- bar for bar pt. 2 - dc2trill lyrics
- русская рулетка (russian roulette) - latz (ru) lyrics
- budućnost je stigla - deca loših muzičara lyrics
- for to the city - family and friends lyrics
- pétard max - bolémvn lyrics
- cuore di ghiaccio - d.a.go lyrics
- i.d.w.f. (i don't wanna fight) - a foreign affair lyrics