lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

owo re - oluwaseun praise lyrics

Loading...

#chorus
iwo ni mo ri
ninu iji
iwo ni mo ri
ninu idanwo
owo re o
lo gbe ogun aye mi mi

#verse
nigba teniyan sebi eniyan
iwo mo ri o
iwo ni mo ri
nigba taye gbona won yo si mi
owo otun oluwa lagbega
owo otun oluwa sagbara o
owo re o
loba mi segun isoro

#chorus
iwo ni mori
ninu iji
iwo ni mo ri
ninu idanwo
owo re o
lo gbe ogun aye mi mi
#verse
owo re lo di mi mu lowo mu wonu ogo
owo re lo re iku koja lori mi
owo re lo gbe ogun aye mi mi patapata
owo re o
lo gbe ogun aye mi mi

#chorus
iwo ni mori
ninu iji
iwo ni mo ri
ninu idanwo
owo re o
lo gbe ogun aye mi mi

verse
(owo re o)
(logbe ogun aye mi mi)
owo re o
lo gbe ogun aye mi mi
(olorun ayodele babalola)
(owo re ni mo ri lojo ogun le)
owo re o
lo gbe ogun aye mi mi
(nigbati isoro de)
(oba aye mi pade lona iyanu)
owo re o
lo gbe ogun aye mi mi
(owo re o)
(logbe ogun aye mi mi)
owo re o
lo gbe ogun aye mi mi
#chorus
iwo ni mori
ninu iji
iwo ni mo ri
ninu idanwo
owo re o
lo gbe ogun aye mi mi

Random Song Lyrics :

Popular

Loading...