oba ni - p. sam lyrics
oba ni lyrics
(chorus)
eba mi pe o
oba ni
oba ni
oba ni
oba nla lo je o
oba ni
pe e oba
ani eba mi pe o
oba ni
oba ni
oba ni
oba nla lo je o
oba ni
pe e oba
(verse 1)
ogbeni nija keru bonija
olorun nla sha ni o
iwo l’olorun ti mo mo
to n gbeja eni
iwo l’olorun ti mo mo
to n toju eni nigbagbo
ijinle ife atofarati o bi oke
oke nla ti n kamo laya jinjin
yagboyaju okunrin ogun
awuwo masegbe
ijinle ife atofarati bi oke
iwo sha l’olorun ti mo mo nigbagbo
(chorus)
eba mi pe o
oba ni
oba ni
oba ni
oba nla lo je o
oba ni
pe e oba
ani eba mi pe o
oba ni ( e pe e)
oba ni
oba ni
oba nla lo je o
oba ni
pe e oba
(verse 2)
i have searched through all thе earth
i have found no one like you
nigbagbo agbaiyе kosi o
oba le o ma je in all circumstances
mo woke
mo wole
mo wotun
mo wosi eh
eyin ni mo ba n be o
if i say make i count your mercy
for my life o o o
i go lose count o
anu re lori mi o
ko se fenuso oh oh oh
(chorus)
oba ni
oba ni
oba ni
oba nla lo je o
oba ni
pe e oba
eba mi pe o
oba ni
oba ni
oba ni
oba nla lo je o
oba ni
pe e oba
(hook)
pe e
oba
oba oba ah
epe e oba
oba nla lo je o
oba ni
ani epe e
oba
oba oba ah
epe e oba
oba nla lo je o
oba ni
(chorus)
eba mi pe o oba ni
oba ni
oba ni
oba nla lo je o
oba ni
pe e oba
oba ni
oba ni
oba ni
oba nla lo je o
oba ni
pe e oba
Random Song Lyrics :
- blasé - warpstr lyrics
- la prima volta - beba lyrics
- inner arts - じん (jin) (jpn) lyrics
- take u down - stract & crzma lyrics
- abandon us - killswitch engage lyrics
- money mode - alin meridiem lyrics
- solo upa (upa) - mc maha lyrics
- cosumed - profiler lyrics
- le rêveur - dick rivers lyrics
- a fools life - q lazzarus lyrics