
atewo - qdot lyrics
kewu ni ma fi wole
kewu ni ma fi wole oh ohhh
ile ologo, ile alayo
kewu ni ma fi wole
achalafuli jarafa karimu
serib-mi serifa seruku
serimoka serifa kalisdada zoli ihh
(chorus)
meta meta latewo iye yi oh-
atewo eh eh iye ehhh, atewo
meta meta latewo iye yi oh-
atewo eh eh iye ehhh, atewo
(verse 2)
ma da faliu, ma da selifa
senseburi molaika
ibura kanka buriji madansimo seliu
k’olosho to di slay mama, ise lo ma se
alert mi ma dun, oju yin lo ma se-
ile o, gboro oluwa, lori re ma se’un ire
omo ologo ma gbera
elohi o, iwo adaba; elohi o, iwo adaba
adaba t’o wa ninu ogba, adaba mimo ni
adaba yi o wole
(chorus)
meta meta latewo iye yi oh-
atewo eh eh iye ehhh, atewo
meta meta latewo iye yi oh-
atewo eh eh iye ehhh, atewo
(verse 3)
b’omi se wonu agbon mi, ko s’eni toye-
olorun o! motelimo sarifa tali
ma je k’aye bu mi pe camera mi o da
ma je k’aye fi mi sesin pe iwa mi o da
olorun mose, omo orimolade tumolase
baba dami lohun; aye mi re, ba mi tunse
elohi o, iwo adaba; elohi o, iwo adaba
adaba t’o wa ninu ogba, adaba mimo ni
adaba yi o wole
(chorus)
meta meta latewo iye yi oh-
atewo eh eh iye ehhh, atewo
meta meta latewo iye yi oh-
atewo eh eh iye ehhh, atewo
(verse 4)
omo cherubim seraphim
you gats to be prayerful
toripe- ibarasa lamalifu
agbara luselifa
serib-mi serifumi elede kewu
ijiria falibu saliabana kalifi
mada selihu lona mefa
mo pasa fowo inu afefe k’o
ma pada sinu afefe mo
Random Song Lyrics :
- paper doll (polskie tlumaczenie) - 山下達郎 (tatsuro yamashita) lyrics
- mach dich locker - dorian grau lyrics
- районная (district) - пилот (pilot) (rus) lyrics
- more to life - sunshine christo lyrics
- três e meia - carolina de deus lyrics
- i'm a six, and she's like a ninety - labit lyrics
- что в мешочке - wa11hаck lyrics
- quiet night - michael vita lyrics
- downstream - georgia alexandra lyrics
- f.a.b. - dave gany lyrics