dewale - rybeena lyrics
dewale
omo iya dewale
dewale
omo iya dewale
dewale
omo iya dewale
dewale
omo iya dewale
salam alaik*m
wa alaik*m salam
mo ki onile
alaremu olorin tajode ni bonsue
omo egba re mi mio le fosi owo juwe
ile baba mi atanda omo subulade
mama mi a ma so fun mi pe o si ma da ( o si ma da)
oni pe inujin kin sora fun onilara (onilara)
mo soko soja ara ile lo farapa
anfani po nbe gidi toba shey dada aa
oremi adun ma de ooh ( adun ma de)
oremi adun ma de ooh ( adun ma de)
ko kin mu latecomer ni ile aye o
oremi adun ma de ooh
oremi adun ma de ooh
oremi adun ma de oo
ko kin mu latecomer ni ile aye o
oremi adun ma de oo
mo gbo pe ee
mo gbo pe
mo gbo pe e tin gba nkan ribiti tin je oko nla
aunty abey nile akoku she n raye
shey e ti gbagbe pe aja to wole tan ekun
shey e o mo pe iku lo n nwa
mo gbo pe ee
mo gbo pe
mo gbo pe e tin gba nkan ribiti tin je oko nla
aunty abey nile akoku she n raye
shey e ti gbagbe pe aja to wole tan ekun
shey e o mo pe iku lo n nwa
aye tamotiye mo beru aye mo safun aye
oju ti rokun rosa e bere mi lowo omotunde
aye tamotiye mo beru aye mo safun aye
oju ti rokun rosa bere mi lowo omotunde
okun ati igba teju si konga tee gboju
esun omi lo lo ree bu wa koju to mo
abelejayan ku ise o emi n mo leja mi
beja jinna a di teleja o
beleja yaan a je oju
oremi adun ma de oo (adun ma de)
oremi adun ma de oo (adun ma de)
ko kin mu late comer ni ile aye o
oremi adun ma de oo
oremi adun ma de oo
oremi adun ma de oo
ko kin mu late comer ni ile aye o
oremi adun ma de oo
Random Song Lyrics :
- nobody's best friend - bambii lyrics
- bruised fruit - st. paul & the broken bones lyrics
- estou vivo - homies 8000 lyrics
- amigo - alonzo lyrics
- border - authentic bros lyrics
- won't change - rico nasty lyrics
- somebody special (acoustic version) - nina nesbitt lyrics
- ortie - thot lyrics
- you do - kings (nz) lyrics
- espiral - santa sabina lyrics