
saworo ilu - teledalase lyrics
saworo ilu
o kin ni isinmi
on ro, on ro, o n ro
on ro, on ro, o n ro
saworo ilu
o kin ni isinmi
on ro, on ro, o n ro
on ro, on ro, o n ro
saworo ilu
o kin ni isinmi
on ro, on ro, o n ro
on ro, on ro, o n ro
saworo ilu
o kin ni isinmi
on ro, on ro, o n ro
on ro, on ro, o n ro
eni peri mi ni ibi
ibi a ba won
eni ro ire si mi o
ire a ba won
mi o ni rele mo o
laye mi
mi o ni fi ikoro saye mi
eni ro ibi si mi o
ibi a ba won
a ti demi laade iye ade ogo
a ti gbemi ro o
a ti somi dotun
a ti demi lamure iye
saworo ilu
o kin ni isinmi
on ro, on ro, o n ro
on ro, on ro, o n ro
saworo ilu
o kin ni isinmi
on ro, on ro, o n ro
on ro, on ro, o n ro
saworo ilu
o kin ni isinmi
on ro, on ro, o n ro
on ro, on ro, o n ro
saworo ilu
o kin ni isinmi
on ro, on ro, o n ro
on ro, on ro, o n ro
eni ro ibi si mi o
ibi a ba won
abe ojiji oluwa ni mo n gbe o
eru o ba mi o
aya o foo mi o
eru o ba mi
mo la alatileyin
nibo lomi ti n bo
ko pada
nibo ni iji ti n bo
ko pada
eni duro d’oluwa
ko ni pofo
eni duro d’oluwa
ko ni pofo
saworo ilu
o kin ni isinmi
on ro, on ro, o n ro
on ro, on ro, o n ro
saworo ilu
o kin ni isinmi
on ro, on ro, o n ro
on ro, on ro, o n ro
ayo ayo ayo
ire ire ire ire ire o o
ogo ogo ogo ogo ogo
lye iye iye iye iye
ire ni temi
ire ni temi
ire ni tomo mi
ire ni tegbon mi
ire ni taburo mi
ire ni ti lya mi
ire ni ti baa mi
ire ire
ire ni ti wa o o o o
Random Song Lyrics :
- i picked c, ain't that a bitch - freaks over there lyrics
- sneak diss - jordan oyk lyrics
- briga me za nju - jelena elena lyrics
- take this slow - yanni 2k lyrics
- doll - annie scherer lyrics
- im sorry - tony mecca iv lyrics
- драма (drama) - вавян и белые тени (vavyan i belye teni) lyrics
- rocket power (intro)* - quavo lyrics
- country home - charlie mars lyrics
- forbidden fruit - mmyykk lyrics