lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

jesu awa yio sin o (ccc hymn 62) - temitope serentainer lyrics

Loading...

jesu
àwa yíò sìn ọ′
jesu
àwa yíò sìn ọ’
n′íbi mímọ’ yìí
l’áàrin ìjọ nlá rẹ
àwa yíò sìn ọ′
títí d′ópin
àwa yíò mú ‘bùkún re′lé
jesu
àwa yíò sìn ọ’
jesu
àwa yíò sìn ọ′
n’íbi mímọ′ yìí
l’áàrin ìjọ nlá rẹ
èmi ó sìn ọ’
títí d′ópin
èmi ó mú ′bùkún re’lé
jesu
àwa yíò sìn ọ′
jesu
àwa yíò sìn ọ’
n′íbi mímọ’ yìí
l′áàrin ìjọ nlá rẹ
àwa yíò sìn ọ’
títí d’ópin
àwa yíò mú ′bùkún re′lé
àmín

Random Song Lyrics :

Popular

Loading...