
ramadan kareem - tolibian, odumodublvck & boj lyrics
[chorus: tolibian]
saari, saari ti to musulumi ẹ didé n’lẹ kẹ jẹun o
ehn, lọsan ramadan
oju mi ti ri lọsan ramadan
b’ọn gb’ounjẹ wa, mi o ni le jẹun
b’ọn gb’omi wa, mi o ni le mu o
agba to l’omi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
[non*lyrical vocals]
[verse 1: odumodublvck]
black sheep forever, black sheep for life
izgaaju ’til we kpeme, antiworld gangsters
ge records, you get me? odumodublvck
kala
musa serve me my saari suya
if that na where my n*ggas dey gather
if you think i’m fapping it, you’re right accordingly
[?]
when you been dey sisi, you dey jolly ramadan kareem (opor)
[?]
[verse 2: tolibian]
l’ale ramadan (ehn)
[?]
l’ale ramadan (ehn)
ibe la ti n ma ṣ’ere pa
l’ale ramadan (eyy)
salam alaik*m, wa alaik*m assalam
e didé, e didé, e didé le
[chorus: tolibian]
saari, saari ti to musulumi ẹ dide n’lẹ kẹ jẹun o
ehn, lọsan ramadan
oju mi ti ri lọsan ramadan
b’ọn gb’ounjẹ wa mi o ni le jẹun
b’ọn gb’omi wa mi o ni le mu o
agba to l’omi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
[non*lyrcal vocals]
[post*chorus: tolibian]
ẹ ye fa baki lọsan ramadan
ẹ ye gb’oloṣo lọsan ramadan
ẹ ma ṣe ṣaṣe ninu ramadan
o ṣi tun wẹ’ṣẹ ninu ramadan
[outro: tolibian]
yeah, yeah, yeah
Random Song Lyrics :
- si no estas - b sanz lyrics
- 기분 좋아지는 노래 (kiki) - sumin (수민) lyrics
- blue corvette - jubël lyrics
- come my way - the tuba room lyrics
- libro sin final parte 3 - temperamento lyrics
- vienjetediunsecret - achim lyrics
- ben kimim - denis seven lyrics
- crucifix - marcusicon lyrics
- nafanua - shepherds reign lyrics
- rak lein nar 2 - khun htetz naing lyrics