lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

jesu orin mi (jesus my song) - ynl sam lyrics

Loading...

{intro}
onisegun nla wa nihin
jesu abanidaro;
oro re mu ni l’ ara da
a, gbo ohun ti jesu!
iro didun l’ orin seraf’
oruko didun li ahon
orin t’ o dun julo ni
jesu! jesu! jesu!

{verse 1}
jesu iwo ni mo fe
(you’re the one i love)
jesu
iwo layo mi
(you’re my joy)
jesu
oluwosan mi
(my healer)
jesu oh jesu oh jesu
olu lana mi jesu
(my way maker)
agbara mi jesu
(my strength)
oluso mi
(my guardian)
jesu oh jesu oh jesu
apata mi jesu
(my rock)
ibi isadi mi jesu
(my fortress)
ife mi
(my love)
jesu oh jesu oh jesu oh
{chorus}
iro didun l’ orin seraf’,
oruko didun li ahon,
orin t’ o dun julo ni,
jesu! jesu! jesu!

iro didun l’ orin seraf’,
oruko didun li ahon,
orin t’ o dun julo ni,
jesu! jesu! jesu!

{verse 2}
talo dabi re
laye ati lorun
talo dabi re
gbo gbo nko loti funmi
nitori jesu
ogba iku mi ku
otu fi eje wemi
eyi ma ni olorun se
ife re por gan
i can’t deny
this love that you love me o
it’s unimaginable unfathomable

{chorus}
iro didun l’ orin seraf’,
oruko didun li ahon,
orin t’ o dun julo ni,
jesu! jesu! jesu!

iro didun l’ orin seraf’,
oruko didun li ahon,
orin t’ o dun julo ni,
jesu! jesu! jesu!

Random Song Lyrics :

Popular

Loading...