lirik lagu happy people – aṣa
o òré mi láídé
níbo ló dà l’ójó sat-rday yìí
hmmm… wón se party níhìn o
l’ókè súnáà léhìn kùlé àwon làtí
ànkárá la dá
kòstúmù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
ànkárá la dá
kòstúmù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
oh we’re happy people
and that’s who we are
we’re having fun
we’re the children of the sun
oh we’re happy people
and that’s who we are
we don’t care
we’re the children of the sun
o òré mi laide
níbo ló kàn l’ójó sunday yìí
hmmm… wón gbéyàwó níhin o
l’ókè pópó légbe ilé àwon toyeeb
ànkárá la dá
kòstúmù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
ànkárá la dá
gèlè búlúù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
oh we’re happy people
and that’s who we are
we’re having fun
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are
we don’t care
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are
we’re having fun
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are
oh we don’t care
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are now
oh we don’t care
we are the children of the sun
lirik lagu lainnya :
- kumpulan lirik lagu kikolo › lirik lagu carotina coccolina – kikolo
- kumpulan lirik lagu lil ricefield › lirik lagu symphony – lil ricefield
- kumpulan lirik lagu forsette › lirik lagu liptonek green tea mmmmm – forsette
- kumpulan lirik lagu lyrics ftb dəliyəm › lirik lagu ftb – dəliyəm (lyrics) – ftb – dəliyəm
- kumpulan lirik lagu finlince › lirik lagu shawty – finlince!
- kumpulan lirik lagu leryx › lirik lagu kung fu – leryx
- kumpulan lirik lagu dannypsyc › lirik lagu hot tamale – dannypsyc
- kumpulan lirik lagu kevin forest › lirik lagu summertime groovin’ – kevin forest
- kumpulan lirik lagu duki › lirik lagu humo* – duki
- kumpulan lirik lagu usain bolt › lirik lagu green stars (yoda diss track) – usain bolt