lirik lagu mímó ni òdó àgùtan – congress musicfactory
mímó ni òdó àgùtan
[akorin}
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[ẹsẹ 1]
gbogbo eda f’ogo fun o
gbogbo okan wa bukun f’oruko re
ede, eya ati awon orile ede
eniyan mimo nkorin iyin re
[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[ẹsẹ 2]
a teriba nibi mimo re
a gbowo s’oke a juba re
oluwa eyin nikan l’owo yi ye
iwo nikan ni gbogbo iyin ye
gbogbo iyin
[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[ipari]
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa to tun nbo waaaa
lirik lagu lainnya :
- kumpulan lirik lagu lewis capaldi › lirik lagu forever (live from wembley) – lewis capaldi
- kumpulan lirik lagu wingz walter iii › lirik lagu kooler than you – wingz & walter iii
- kumpulan lirik lagu kyenn › lirik lagu pnkovr – kyenn
- kumpulan lirik lagu the buzz › lirik lagu 3 is a magic number – the buzz
- kumpulan lirik lagu amuly › lirik lagu gata – amuly
- kumpulan lirik lagu an bokjin › lirik lagu about love (narr. version) – an bokjin
- kumpulan lirik lagu darnel neel › lirik lagu won’t be moved – darnel neel
- kumpulan lirik lagu kenny golder jr › lirik lagu zooted – kenny golder jr.
- kumpulan lirik lagu monet192 › lirik lagu hollywood – monet192
- kumpulan lirik lagu snake eyes › lirik lagu big deal – snake eyes