lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

imole aye (light of the world) - kharisma lyrics

Loading...

[intro]
oh oh… oh… oh oh… yeah
eh eh eh… eh eh

[verse 1]
kini’ba shey bi kò sì re o
ìrè l’eni tó gbà mí lá
èmi kèfèrí tó gbà sínú ẹbí re ooo (yeah)
ore*ofe ni mo fi ngbé inú re o
kí ma yí shey nipa ti ìṣe
ìwọ deni ìmolè a rayé ooo (yeah)
àti tìkòṣe ni òrò wa
òrò sì n’ bẹ pẹ̀lú ọlọ́run
ọlọ́run sì ni òrò náà oo (yeah)
nínú re ni ìyè wà
ìyè náà sì ni ìmolè a rayé
ìmolè yìí tan nínú òkùnkùn
òkùnkùn sì paràdà ooo (yeah)

[chorus]
èmi ni ìmolè ayé
èmi ni ìmolè ayé ooo
jesu ni ìmolè ayé eee
òun ni ìmolè ooooo (×2)

[bridge]
ehhhhhhhhh
ehhhhh (tongues)
ohhhhh (tongues)
[verse 2]
let your light so shine forth to the world
no man can put on the light
and put it in a bushel
let your light so shine to the world
oh oh oh oh… eh

chorus (repeat)
èmi ni ìmolè ayé
èmi ni ìmolè ayé ooo
jesu ni ìmolè ayé eee
òun ni ìmolè (eh eh eh)

outro
(tongues…)

Random Song Lyrics :

Popular

Loading...