lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu nitori awa – king sunny ade

Loading...

wan lọ gb′ẹbọ ni oríta mẹta
nitori awa
wan ko jẹ ki babalawo ko simi lalẹ

nitori awa
wan ba kuro ni shọshi wan gba’le ra daun shelọ
nitori awa
eku ina′wo ẹran pipa l’ojo jumọ
nitori awa
wan ma gb’ẹbọ wan ni ihoho lo gan jọ oru
nitori awa
t′aba wi tan wan ma gbe bíbélì ọrọ kiri
nitori awa

kuru kẹrẹ, o di ′le alawo
kuru kẹrẹ
kuru kẹrẹ, o di ‘le oniṣegun
ogun o ran wa o
ẹ ma wulẹ sáré ka

kuru kẹrẹ, o di ′le alawo
kuru kẹrẹ
kuru kẹrẹ, o di ‘le oniṣegun
ogun o ran wa o
ẹ ma wulẹ sáré ka

lirik lagu lainnya :

YANG LAGI NGE-TRENDS...

Loading...