
gbo gbo wa la fine : a letter to the beauty police - tobiloba lyrics
bi mo ba kola
se mo fine?
bi mo ba bula
se mo fine?
bi mo ba pupa
se mo fine?
bi mo ba sanra
se mo fine?
bi mo ba dudu
se mo fine?
ti mo tun tirin
se mo fine ?
ti ara mi o ba pe
se mo fine?
tin nkan nkan o ba to
se mo fine?
abi awon kan nikan ni
ni kan ni
abi awon kan nikan ni
ni kan ni
gbo gbo wa la fine
gbo gbo wa la fine
gbo gbo wa la fine
(you know i’m talking to you)
gbo gbo wa la fine
bi mo ba kere?
se mo fine?
ti mo really kere
se mo fine?
bi mo ba pelebe
se mo fine?
ti mio tie ni curve?
se mo fine?
bi mio ba nirun?
se mo fine?
ti mo ni desеrt
se mo fine?
bi mo ba je afin
sе mo fine?
ti mo je rara
se mo fine?
abi awon kan nikan ni
ni kan ni
abi awon kan nikan ni
ni kan ni
gbo gbo wa la fine
(you know i’m talking to you)
gbo gbo wa la fine
(you know i’m talking to you)
gbo gbo wa la fine
(you know i’m talking to you)
gbo gbo wa la fine
gbo gbo wa la
don’t let your insecurities
tie you to a spot
don’t let whatever industry
determine what you are worth
don’t let your insecurities
tie you to a spot
don’t let whatever industry
determine what you are worth
don’t let your insecurities
tie you to a spot
don’t let whatever industry
determine what you are worth
la fine
gbo gbo wa la fine
gbo gbo wa la fine
gbo gbo wa la fine
gbo gbo wa la fine
Random Song Lyrics :
- halt deine fresse - bass sultan hengzt lyrics
- alive with you - clngr lyrics
- born of a hanged corpse - strychnia lyrics
- rock & sock - michael christmas lyrics
- joya - fayzen lyrics
- just us - the weather girls lyrics
- kommer over det - shaka loveless lyrics
- dollalalalala lotsa paypa - mac dre lyrics
- break it slow - the mess lyrics
- multis bish - dyaz the bringer of love n peace lyrics